THESE ARE NAMES OF GOD IN YORUBA.
The translations are so amazingly beautiful...
1. Oluwa,
(Lord)
2. Oluwa
wa, (Our Lord)
3. Olorun,
(God)
4. Olorun
wa, (Our God)
5. Oluwa
awon oluwa, (The Lord of lords)
6. Olorun
awon olorun, (The God of gods)
7. Kabiyeesi,
(The King)
8. Oba
awon oba,( King of kings)
9. Olodumare,(
The Almighty)
10. Arugbo
ojo,(Ancient of days)
11. Olorun
agbalagba,( Ancient of days)
12. Adagba
ma paaro oye,(Unchanging God)
13. Olorun
ti o yipada, (Unchanging God)
14. Olorun
kan lailai,( The only God)
15. Ikan
lana,(Same yesterday)
16. Ikan
loni, (Same today)
17. Ikan
lola, (Same tomorrow)
18. Okan
titi aye ainipekun, ( The same forever)
19. Oba
ti mbe nibi gbogbo nigba gbogbo,( the ubiquitous God)
20. Metalokan,(
The trinity)
21. Olorun
Baba,(God the Father)
22. Olorun
Omo,(God the son)
23. Olorun
Emi Mimo, (God the Holy spirit)
24. Olorun
Abrahamu, (God of Abraham)
25. Olorun
Isaki, (God of Isaac)
26. Olorun
Jakobu, (God of Jacob)
27. Olorun
owu,(The jealous God)
28. Olorun
ti kii s'enia ti yio paro, (God that is not man that could change)
29. Alewilese,
(He that can Speak and Act)
30. Aleselewi,
(He that can Act and Speak)
31. Owibee
sebee, (He that Speaks and Acts)
32. Awimayehun,
( He who Speaks and does not change His words)
33. Asoromaye,
(He who prophesize and comes to past)
34. Onimajemu,(
Covenant keeping God)
35. Olulana,(The
wonderful way maker)
36. Olorun
oro (Word), (The God of spoken word)
37. Oba
to ti o gbe oro Re ga ju Oruko Re lo, (The God who exalts his word more that
his name)
38. Olutoju
wa, (Our Keeper)
39. Onibuore,(God
whose barn is full of blessing)
40. Afunni
ma s’iregun,(The God who blesses without asking for reward)
41. Adanimagbagbe,
(The creator who never forgets the created)
42. Oyigiyigi,
(Great and Mighty)
43. Alakoso
orun at’aye, (The God of Heaven)
44. Atogbojule,(Dependable
God)
45. Alagbawi
eda,(Defender)
46. Alagbada
ina, (He that covers Himself with fire branded robe)
47. Alawotele
oorun,(He whose underwear is Sun)
48. Asorodayo,(The
God who gives joy)
49. Oba
t'o mu 'banuje tan,(God who puts end to sorrow)
50. Ogbeja
k'eru o ba onija,(God who fights for the defenseless)
51. Jagunjagun
ode orun,(The great warrior of heaven)
52. Olowogbogboro,(God
whose hand is long enough to reach at any length)
53. Olorun
awon omo ogun,(The great warrior)
54. Aduro
tini bi akoni eleru,(The faithful God)
55. Eru
jeje l'eti okun pupa,( The Most powerful by the red sea)
56. Oba
t'o mu iji dake roro,(God who commands the storm, peace be still)
57. Alaabo,(Our
keeper)
58. Oluso,(Our
guard)
59. Olupamo,(Our
keeper)
60. Oludande,(Our
deliverer)
61. Olugbala,(Our
saviour)
62. Olutusile,(God
of freedom)
63. Oludariji,(Our
forgiver)
64. Oba
t'o se'gun agbara ese, (God who delivers from hold of sin)
65. Oba
t'o san gbogbo 'gbese wa,(God who pays the price for our sins)
66. Olorun
ajinde,(The resurrected Lord)
67. Olutunu,(Our
comforter)
68. Olufe
okan wa,(My lover)
69. Oba
t'o yan wa fe,(God who has predestined us)
70. Olusegun,(The
conqueror)
71. Ajasegun,
(The conqueror)
72. Gbanigbani
ni'jo ogun le,(Our defense in time of war)
73. Ogbagba
ti ngb'ara adugbo,( The Protector)
74. Oba
t'o pin okun pupa n'iya,( God who parted the red sea)
75. Olorun
t'o mu Jodani sa niwaju awon omo Re, (God who parted the river Jordan)
76. Oba
t'o bi odi Jeriko wo,(God who fell down the walls of Jericho)
77. Olorun
t'o kolu Egipiti l'ara awon akobi re,(God who killed the first born of the
Egyptians)
78. Oba
t'o ju gbogbo orisa lo,(The Almighty God)
79. Olorun
t'o tobi ju gbogbo aye lo,(Greater than all the earth)
80. Oba
t'o da monamona fun ojo, (The God who created lightening for the rain)
81. Aimope
ani oje,
82. Oba
to j'ewe at'egbo lo,
83. Oba
to ni owa t'owa,(The God who commands)
84. Oba
t'oni olo, t'olo, (The God who commands)
85. Oba
t'oni k'owa, t'owa, (The God who commands)
86. Oba
t'oni k'omasi, ti o si si mo,(The God who can close a door and no man can open)
87. Oba
t'ao ri, sugbon t'ari ise owo Re,(The unseen God but we can feel his impact)
88. Olorun
t'o n gbo adura, (God who hears prayers)
89. Oba
t'o n dahun adura, (Prayer answering God)
90. Olorun
t'ape t'o n je,(The God that you can call and he will answer)
91. Oba
t'o n dahun adura pelu ina,(God that answered by fire)
92. Eleda,(Creator)
93. Akoda
aye,(The first among all things)
94. Aseda
orun,(He established the heavens)
95. Oba
t'o fi'di aye s'ole s'ori omi,( He who established the earth on waters)
96. Oba
t'o mo wa (The Potter),
97. Oba
t'o mo wa ( He that knoweth us),
98. Oba
t'o mo ohun gbogbo,(The all knowing God)
99. Olorun
t'o le se ohun gbogbo,(God who can do all things)
100. Oba
ti ohun gbogbo nbe n'ikawo Re,(God who has the whole world in his hands)
101. Oba
to joko soke orun to f'ile aye se itise Re,(He makes the heaven his seat and
the earth his foot stool)
102. Oba
ti ntu won ka nibi ti won nti da'na iro,(He who causes confusion in the camp of
the enemy)
103. Atererekariaye,(He
spreads out across the earth)
104. Eletigb'aroye,(The
great hear that hears all over the world)
105. Alatilehin,(Our
succor)
106. Alaanu,(Merciful
God)
107. Oba
ti aanu Re duro lailai,(God whose mercies endureth for ever)
108. Oba
alade alafia,(The Prince of peace)
109. Oloore
ofe,(The gracious god)
110. Olorun
ife,(The God of Love)
111. Olorun
ayo,(The God that gives Joy)
112. Olutunu,(Comforter)
113. Olubukun,(The
blessed God)
114. Onise
iyanu,(Miracle worker)
115. Onise
ara,(Wonderful)
116. Onise
nla,(Great God)
117. Mimo,
Mimo, Mimo,(Holy! Holy! Holy)
118. Oba
t'o ninu mimo,(Righteous God)
119. Oba
alaya funfun,(Immaculate God)
120. Ologo
meta, (The Trinity)
121. Olotito,(The
Truthful)
122. Olododo,(The
Truthful)
123. Iye,(Resurrection)
124. Aduro
gboingboin lehin asotito,(Defender of the Truthful)
125. Imole
ninu okunkun aye,(The light in darkness)
126. Alagbara
l'orun ati l'aye,(Mighty in heaven and on the earth)
127. Oba
ti nyoni kuro ninu ofin aye,(God who rescues from the dungeon)
128. Atofarati,(Our
defense)
129. Atogbokanle,(The
trustworthy God)
130. Atofokante,(Our
Confidant)
131. Adunbarin,(Worthy
to walk with)
132. Adunbalo,
(Worthy to follow)
133. Adunkepe,(God
you can call on)
134. Apata
ayeraye,(The rock of ages)
135. Atobiju,(The
Almighty)
136. Atofarati
bi oke,(Our support and defense)
137. Apata
wa,(Our rock of Ages)
138. Odi
wa,(Our shield)
139. Alabarin
aye wa, (Our companion)
140. Olupese,(Our
provider)
141. Olugbega,(The
lifter of our head)
142. Oluranlowo,(Our
help)
143. Ireti
wa,(Our hope)
144. Olu
aye,(God on earth)
145. Olu
orun,(God in heaven)
146. Oba
ti gbobo oba nt'owo Re gb'ase,(Kings from whom kings take directives)
147. Adakedajo,
(He who Judges silently)
148. Adajo
ma fi t'enikan se,(The just Judge)
149. Oba
ti kii s'ojusaju,(The just God)
150. Oba
t'enikan o le pe l'ejo,(The king that can not be judged)
151. Oba
aseyiowu,(Unquestionable God)
152. Oba
tii s'agan d'olomo,(The God who opens the womb of the barren)
153. Abiyamo
ode orun,(The great mother of heaven)
154. Atorise,(God
who can turn bad situation to good)
155. As'oloriburuku
d'olorire,(God who can remove the inadequacies from ones life)
156. Arinu
r'ode,(God who sees the visible and the invisible,)
157. Olumoranokan
eda, (He who sees the intent of the heart of man)
158. Oludamoran
(The Great adviser)
159. Baba
wa,(Abba father)
160. Ore
wa,(Our friend)
161. Ibi
isadi wa,(Our refugee)
162. Aabo
wa,(our protector)
163. Oluwosan,(the
healer)
164. Asoku
d'alaye,(He who brings the dead to life)
165. Olorun
alaaye,(God of the living)
166. Oba
ti n p'ojo iku da,(God who can change appointment with death)
167. Oba
ti emi gbogbo enia wa l'owo Re,( He who has the keys to our existence)
168. Oba
ti nti t'enikan o lesi,(He who shuts and no one can open)
169. Oba
ti nsi t'enikan o leti,(He who opens and no one can close)
170. Awamaridi,(Unsearchable
God)
171. Eleruniyin,
172. Abetilukara
bi ajere,(God who is all ears)
173. Aiku,(Living
God)
174. Aisa,(Faithful)
175. Oba
ti ki sun, ti ki togbe (The king that neither sleeps nor slumbers)
176. Oba
onise nla,(The great worker of good)
177. Onigbonwo
wa, (Our sponsor)
178. Olorun
pipe,(Perfect God)
179. Olorun
rere,(Good God)
180. Akiri
s'ore,(He who goes about doing good)
181. As'ore
kiiri, ,(He who goes about doing good)
182. Gbongbo
idile Jesse,(The root of the tribe of Jesse)
183. Oba
t'o f'oro da ile aye,(He that created all things by his spoken word)
184. Oba
to ti wa k'aye o towa,(He who was in existence before creation)
185. Oba
ti o ma wa nigba t'aye o ni si mo,(He who will remain at the end of all things)
186. Oloruko
nla,(The great name)
187. Ologojulo,(The
glorious God)
188. Emi
ni ti nje Emi ni,(I am the I am)
189. Oba
t'oni gbogbo ope,(He who deserves all praise)
190. Olorun
t'oni gbogbo iyin, ,(He who deserves all honour)
191. Oba
ti ko ni pin ogo Re pel’enikankan,(God that does not share his glory with any
man)
192. Oba
t'o ti wa, t'o si wa, ti o si ma wa lailai, (The God that was, that is and that
will remain for ever)
193. Ibere
ati opin,(The Alpha and omega)
194. OBA
AKIKITAN,(Eternity will not be enough to praise and honour you, O Lord)
No comments:
Post a Comment